Asake - 2:30 Mp3 Download

Here are the complete lyrics to “2:30” by Asake. I hope you enjoy the lyric and share them with others. In case you have not listened to the song “2:30” stream below and download also mp3 song.

Asake – 2:30 Lyrics

[Intro]
Uh
Obah
What dem a say?
Obah
Run
Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm

[Verse 1]
Awa de, awa de de
Awa lọmọ to n sọ ti o seke, ye
Orimọlade gbemi debẹ
Jigan jigan
Ẹsẹ mi o delẹ, delẹ
Alaye mi stop shebẹ
O fẹ jenbi, otun fẹ jenbẹ
Opọ se
Agbawo, fẹnu fo fence
Sun sẹ yin
Amọrawa, sho get?
Abinibi yato s’ability
Ẹsọ fun wọn tan ba teri si
Wọn ma pa lori
Tẹnu kọ, emi promising
Awọn tẹ fọ fun, fọ fun mi
Tori ko sẹ lomi
Many many fẹ dabi mi
Eri bi
Ẹgbọlorun tobi
Mo da aso-ẹbi for my country
You can call me Mr Money

Advertisements

[Chorus]
Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹlu
Oya ka turn up
Kilẹ to mọ
Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
Ye, ye, ye
2:30 fẹlu (Thirty fẹlu)
Oya ka turn up
Kilẹ to mọ

[Verse 2]
Ere moba wa kosi ja
Shokoto pen pe, ye
Ayenika, yebo, yeba
Formation logba, ye ja
Ọmọ’yami ko stay wise
Tranquility, tranquility
I no get time to dey form activity
Kole kalas, I dey find stability
Like abacha, monеy long infinity
What’s the chances?
What’s the probability?
To see a bеtter version of me with agility
No you can’t fake reality
Ogun, principality and calamity
Mo ti lọ, mo ti pa iyen ti
Bẹbẹ no de for jiji
O shi wa n titi
Still get money like Fifty
Dripping like Fiji
I be real G

READ ALSO:  Wande Coal - Ebelebe ft Wizkid Lyrics

[Chorus]
Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹlu
Oya ka turn up
Kilẹ to mọ
Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
Ye, ye, ye
2:30 fẹlu
Oya ka turn up
Kilẹ to mọ

Advertisements